Isa 10:33-34
Isa 10:33-34 Bibeli Mimọ (YBCV)
Kiyesi i, Oluwa, Oluwa awọn ọmọ-ogun yio fi ẹ̀ru wọ́n ẹka: ati awọn ti o ga ni inà li a o ke kuro, ati awọn agberaga li a o rẹ̀ silẹ. On o si fi irin ke pantiri igbó lu ilẹ, Lebanoni yio si ṣubu nipa alagbara kan.
Pín
Kà Isa 10