Ẹ wò ó! OLUWA, OLUWA àwọn ọmọ ogun, yóo gé àwọn ẹ̀ka igi náà pẹlu agbára tí ó bani lẹ́rù. Yóo gé àwọn tí ó ga fíofío lulẹ̀, yóo sì rẹ àwọn agbéraga sílẹ̀. Yóo fi àáké gé àwọn igi igbó tí ó dí, Lẹbanoni pẹlu gbogbo igi ńláńlá rẹ̀ yóo sì wó.
Kà AISAYA 10
Pín
Fi gbogbo Èyá wéra: AISAYA 10:33-34
Ṣe àfipamọ́ àwọn ẹsẹ, kàá ní aìsìní orí ayélujára, wo àwọn àgékúrú ìkọ́ni, àti díẹ̀ síi!
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò