II. Sam 5:3-4
II. Sam 5:3-4 Bibeli Mimọ (YBCV)
Gbogbo agba Israeli si tọ ọba wá ni Hebroni, Dafidi ọba si ba wọn ṣe adehun kan ni Hebroni, niwaju Oluwa: nwọn si fi ororo yan Dafidi li ọba Israeli. Dafidi si jẹ ẹni ọgbọn ọdun nigbati o jọba; on si jọba li ogoji ọdun.
Pín
Kà II. Sam 5II. Sam 5:3-4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YCB)
Gbogbo àgbàgbà Israẹli sì tọ ọba wá ní Hebroni, Dafidi ọba sì bá wọn ṣe àdéhùn kan ní Hebroni, níwájú OLúWA: wọ́n sì fi òróró yan Dafidi ní ọba Israẹli. Dafidi sì jẹ́ ẹni ọgbọ̀n ọdún nígbà tí ó jẹ ọba; ó sì jẹ ọba ní ogójì ọdún.
Pín
Kà II. Sam 5II. Sam 5:3-4 Bibeli Mimọ (YBCV)

Kà II. Sam 5