2 Samuẹli 5:3-4

2 Samuẹli 5:3-4 YCB

Gbogbo àgbàgbà Israẹli sì tọ ọba wá ní Hebroni, Dafidi ọba sì bá wọn ṣe àdéhùn kan ní Hebroni, níwájú OLúWA: wọ́n sì fi òróró yan Dafidi ní ọba Israẹli. Dafidi sì jẹ́ ẹni ọgbọ̀n ọdún nígbà tí ó jẹ ọba; ó sì jẹ ọba ní ogójì ọdún.