Saamu 86:8

Saamu 86:8 YCB

Nínú àwọn òrìṣà kò sí ẹni tí ó dàbí i rẹ, OLúWA: kò sí àwọn iṣẹ́ tí a lè fiwé tìrẹ.