Saamu 86:5-7

Saamu 86:5-7 YCB

Ìwọ ń dáríjì, ìwọ sì dára, OLúWA, ìwọ sì ṣàánú fún gbogbo àwọn tí ń ké pè ọ́, Gbọ́ àdúrà mi, OLúWA; tẹ́tí sí ẹkún mi fún àánú. Ní ọjọ́ ìpọ́njú mi èmi yóò pè ọ́, nítorí ìwọ yóò dá mi lóhùn.