Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ni ó ń sọ ní ti tèmi, pé “Ọlọ́run kò nígbà á là.” Sela. Ṣùgbọ́n ìwọ ni asà yí mi ká, OLúWA; ìwọ fi ògo fún mi, ìwọ sì gbé orí mi sókè. OLúWA ni mo kígbe sókè sí, ó sì dá mi lóhùn láti orí òkè mímọ́ rẹ̀ wá. Sela. Èmi dùbúlẹ̀, mo sì sùn; mo sì tún padà jí, nítorí OLúWA ni ó ń gbé mi ró.
Kà Saamu 3
Feti si Saamu 3
Pín
Fi gbogbo Èyá wéra: Saamu 3:2-5
Ṣe àfipamọ́ àwọn ẹsẹ, kàá ní aìsìní orí ayélujára, wo àwọn àgékúrú ìkọ́ni, àti díẹ̀ síi!
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò