Saamu 140:6-7

Saamu 140:6-7 YCB

Èmi wí fún OLúWA pé ìwọ ni Ọlọ́run mi; OLúWA, gbọ́ ohùn ẹ̀bẹ̀ mi. OLúWA Olódùmarè, agbára ìgbàlà mi, ìwọ ni ó bo orí mi mọ́lẹ̀ ní ọjọ́ ìjà.