ORIN DAFIDI 140:6-7

ORIN DAFIDI 140:6-7 YCE

Mo wí fún OLUWA pé, “Ìwọ ni Ọlọrun mi.” OLUWA, tẹ́tí sí ohùn ẹ̀bẹ̀ mi. OLUWA, OLUWA mi, alágbára tíí gbani là, ìwọ ni o dáàbò bò mí ní ọjọ́ ogun.