Kíyèsi, ó ti dára ó sì ti dùn tó fún àwọn ará láti máa jùmọ̀ gbé ní ìrẹ́pọ̀. Ó dàbí òróró ìkunra iyebíye ní orí, tí ó sàn dé irùngbọ̀n, àní irùngbọ̀n Aaroni: tí ó sì sàn sí etí aṣọ sórí rẹ̀; Bí ìrì Hermoni tí o sàn sórí òkè Sioni. Nítorí níbẹ̀ ní OLúWA gbé pàṣẹ ìbùkún, àní ìyè láéláé.
Kà Saamu 133
Feti si Saamu 133
Pín
Fi gbogbo Èyá wéra: Saamu 133:1-3
Ṣe àfipamọ́ àwọn ẹsẹ, kàá ní aìsìní orí ayélujára, wo àwọn àgékúrú ìkọ́ni, àti díẹ̀ síi!
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò