Saamu 130:1-2

Saamu 130:1-2 YCB

Láti inú ibú wá ni èmi ń ké pè é ọ́ OLúWA OLúWA, gbóhùn mi, jẹ́ kí etí rẹ kí o tẹ́ sílẹ̀ sí ohùn ẹ̀bẹ̀ mi.