LATI inu ibu wá li emi kepe ọ, Oluwa. Oluwa, gbohùn mi, jẹ ki eti rẹ ki o tẹ́ silẹ si ohùn ẹ̀bẹ mi.
Ninu ìṣòro ńlá ni mò ń ké pè ọ́, OLUWA! OLUWA, gbóhùn mi, dẹtí sí ohùn ẹ̀bẹ̀ mi.
Láti inú ibú wá ni èmi ń ké pè é ọ́ OLúWA OLúWA, gbóhùn mi, jẹ́ kí etí rẹ kí o tẹ́ sílẹ̀ sí ohùn ẹ̀bẹ̀ mi.
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò