ORIN DAFIDI 130:1-2

ORIN DAFIDI 130:1-2 YCE

Ninu ìṣòro ńlá ni mò ń ké pè ọ́, OLUWA! OLUWA, gbóhùn mi, dẹtí sí ohùn ẹ̀bẹ̀ mi.