Saamu 118:7

Saamu 118:7 YCB

OLúWA ń bẹ fún mi; òun ni olùrànlọ́wọ́ mi Nítorí náà ni èmi ó ṣe rí ìṣẹ́gun mi lórí àwọn tí ó kórìíra mi.