← Àwon ètò
Àwọn ètò kíkà ọ̀fé àti àyọkà tó ní ṣe pẹ̀lú O. Daf 118:7
Mọ Ohùn Ọlọ́run // Kọ́ L'áti Pàdé Rẹ̀
Ọjọ́ Mẹ́rìn
Ohùn Ọlọ́run lè wá bíi ọ̀rọ̀ kẹ́lẹ́kẹ́lẹ́ tàbí ìró ìjì líle. Ohun gbòógì ni l'áti dá a mọ̀, bí ó ti wù kí ó wá—àti kí a gbàgbọ́ wí pé Ó dára, wí pé Ó tóbi ju èyíkéyìí àwọn ìjàkadì wa lọ. Bẹ̀ẹ̀rẹ̀ ètò ọlọ́jọ́ mẹ́rin yìí kí o sì bẹ̀ẹ̀rẹ̀ síí kọ́ bí a ṣe lè pàdé Rẹ̀, ohùn Rẹ̀, ìwàláàyè Rẹ̀ —kí o sì da ara pọ̀ mọ́ ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọkùnrin àti obìnrin tí ń ní ìrírí Rush |Ẹ̀mí Mímọ́ Ní Ayé Òde-Òní.