Lefitiku 19:1-2

Lefitiku 19:1-2 YCB

OLúWA sọ fún Mose pé, “Bá gbogbo àpéjọpọ̀ àwọn ọmọ Israẹli sọ̀rọ̀, sì wí fún wọn pé: ‘Ẹ jẹ́ mímọ́ nítorí Èmi OLúWA Ọlọ́run yín jẹ́ mímọ́.