Lef 19:1-2
Lef 19:1-2 Yoruba Bible (YCE)
OLUWA sọ fún Mose pé kí ó sọ fún ìjọ eniyan Israẹli pé “Ẹ jẹ́ mímọ́, nítorí pé, mímọ́ ni èmi OLUWA Ọlọrun yín.
Pín
Kà Lef 19OLUWA sọ fún Mose pé kí ó sọ fún ìjọ eniyan Israẹli pé “Ẹ jẹ́ mímọ́, nítorí pé, mímọ́ ni èmi OLUWA Ọlọrun yín.