LEFITIKU 19:1-2

LEFITIKU 19:1-2 YCE

OLUWA sọ fún Mose pé kí ó sọ fún ìjọ eniyan Israẹli pé “Ẹ jẹ́ mímọ́, nítorí pé, mímọ́ ni èmi OLUWA Ọlọrun yín.