Ẹkun Jeremiah 3:31-33

Ẹkun Jeremiah 3:31-33 YCB

Ènìyàn kò di ìtanù lọ́dọ̀ Olúwa títí láé. Lóòtítọ́ ó mú ìbànújẹ́ wá, yóò fi àánú hàn, nítorí títóbi ni ìfẹ́ rẹ̀. Nítorí kò mọ̀ ọ́n mọ̀ mú ìpọ́njú wá tàbí ìrora wá fún ọmọ ènìyàn.