Oniwaasu 11:7-8

Oniwaasu 11:7-8 YCB

Ìmọ́lẹ̀ dùn; Ó sì dára fún ojú láti rí oòrùn. Ṣùgbọ́n jẹ́ kí ènìyàn jẹ̀gbádùn gbogbo iye ọdún tí ó le è lò láyé ṣùgbọ́n jẹ́ kí ó rántí ọjọ́ òkùnkùn nítorí wọn ó pọ̀ Gbogbo ohun tí ó ń bọ̀ asán ni.