Oni 11:7-8

Oni 11:7-8 YBCV

Nitõtọ imọlẹ dùn ati ohun didara ni fun oju lati wò õrùn. Ṣugbọn bi enia wà li ọ̀pọlọpọ ọdun, ti o si nyọ̀ ninu gbogbo wọn, sibẹ, jẹ ki o ranti ọjọ òkunkun pe nwọn o pọ̀. Ohun gbogbo ti mbọ̀, asan ni.