Ìṣe àwọn Aposteli 8:36

Ìṣe àwọn Aposteli 8:36 YCB

Bí wọ́n sì tí ń lọ lọ́nà, wọ́n dé ibi omi kan; ìwẹ̀fà náà sì wí pé, “Wò ó, omi nìyí. Kín ni ó dá mi dúró láti bamitiisi?”