Iṣe Apo 8:36
Iṣe Apo 8:36 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YCB)
Bí wọ́n sì tí ń lọ lọ́nà, wọ́n dé ibi omi kan; ìwẹ̀fà náà sì wí pé, “Wò ó, omi nìyí. Kín ni ó dá mi dúró láti bamitiisi?”
Pín
Kà Iṣe Apo 8Iṣe Apo 8:36 Bibeli Mimọ (YBCV)
Bi nwọn si ti nlọ li ọ̀na, nwọn de ibi omi kan: iwẹfa na si wipe, Wò o, omi niyi; kili o dá mi duro lati baptisi?
Pín
Kà Iṣe Apo 8