O. Sol 5:10-11

O. Sol 5:10-11 YBCV

Olufẹ mi funfun, o si pọn, on ni ọlá jù ọ̀pọlọpọ lọ. Ori rẹ̀ dabi wura ti o dara julọ, ìdi irun rẹ̀ dabi imọ̀ ọpẹ, o si du bi ẹiyẹ iwò.