O. Sol 5:10-11
O. Sol 5:10-11 Bibeli Mimọ (YBCV)
Olufẹ mi funfun, o si pọn, on ni ọlá jù ọ̀pọlọpọ lọ. Ori rẹ̀ dabi wura ti o dara julọ, ìdi irun rẹ̀ dabi imọ̀ ọpẹ, o si du bi ẹiyẹ iwò.
Pín
Kà O. Sol 5Olufẹ mi funfun, o si pọn, on ni ọlá jù ọ̀pọlọpọ lọ. Ori rẹ̀ dabi wura ti o dara julọ, ìdi irun rẹ̀ dabi imọ̀ ọpẹ, o si du bi ẹiyẹ iwò.