O. Daf 77:10-12

O. Daf 77:10-12 YBCV

Emi wipe, Eyi li ailera mi! eyi li ọdun ọwọ ọtún Ọga-ogo! Emi o ranti iṣẹ Oluwa: nitõtọ emi o ranti iṣẹ iyanu rẹ atijọ. Ṣugbọn emi o ma ṣe àṣaro gbogbo iṣẹ rẹ pẹlu, emi o si ma sọ̀rọ iṣẹ rẹ.