O. Daf 77:10-12
O. Daf 77:10-12 Bibeli Mimọ (YBCV)
Emi wipe, Eyi li ailera mi! eyi li ọdun ọwọ ọtún Ọga-ogo! Emi o ranti iṣẹ Oluwa: nitõtọ emi o ranti iṣẹ iyanu rẹ atijọ. Ṣugbọn emi o ma ṣe àṣaro gbogbo iṣẹ rẹ pẹlu, emi o si ma sọ̀rọ iṣẹ rẹ.
Pín
Kà O. Daf 77O. Daf 77:10-12 Bibeli Mimọ (YBCV)
Emi wipe, Eyi li ailera mi! eyi li ọdun ọwọ ọtún Ọga-ogo! Emi o ranti iṣẹ Oluwa: nitõtọ emi o ranti iṣẹ iyanu rẹ atijọ. Ṣugbọn emi o ma ṣe àṣaro gbogbo iṣẹ rẹ pẹlu, emi o si ma sọ̀rọ iṣẹ rẹ.
Pín
Kà O. Daf 77O. Daf 77:10-12 Yoruba Bible (YCE)
Nígbà náà ni mo wí pé, “Ohun tí ó bà mí lọ́kàn jẹ́ ni pé Ọ̀gá Ògo kò jẹ́wọ́ agbára mọ́.” N óo ranti àwọn iṣẹ́ OLUWA, àní, n óo ranti àwọn iṣẹ́ ìyanu ìgbàanì. N óo máa ṣe àṣàrò lórí gbogbo iṣẹ́ rẹ; n óo sì máa ronú lórí àwọn iṣẹ́ ribiribi tí o ṣe.
Pín
Kà O. Daf 77