O. Daf 104:5-7

O. Daf 104:5-7 YBCV

Ẹniti o fi aiye sọlẹ lori ipilẹ rẹ̀, ti kò le ṣipò pada lailai. Iwọ fi ibu omi bò o mọlẹ bi aṣọ: awọn omi duro lori òke nla. Nipa ibawi rẹ nwọn sá; nipa ohùn ãra rẹ, nwọn yara lọ.