ORIN DAFIDI 104:5-7

ORIN DAFIDI 104:5-7 YCE

Ìwọ tí o gbé ayé kalẹ̀ lórí ìpìlẹ̀ rẹ̀, tí kò sì le yẹ̀ laelae. O fi ibú omi bò ó bí aṣọ, omi sì borí àwọn òkè ńlá. Nígbà tí o bá wọn wí, wọ́n sá, nígbà tí o sán ààrá, wọ́n sá sẹ́yìn.