Owe 7:8-9

Owe 7:8-9 YBCV

O nkọja lọ ni igboro li eti igun ile rẹ̀; o si lọ si ọ̀na ile rẹ̀, Ni wiriwiri imọlẹ, li aṣãlẹ, li oru dudu ati òkunkun