Owe 30:21-23

Owe 30:21-23 YBCV

Nitori ohun mẹta, aiye a di rũru, ati labẹ mẹrin ni kò le duro. Iranṣẹ, nigbati o jọba; ati aṣiwère, nigbati o yo fun onjẹ; Fun obinrin, ti a korira, nigbati a sọ ọ di iyale; ati fun iranṣẹbinrin, nigbati o di arole iya rẹ̀.