ÌWÉ ÒWE 30:21-23

ÌWÉ ÒWE 30:21-23 YCE

Àwọn nǹkankan wà tíí mi ilẹ̀ tìtì, ọ̀pọ̀ nǹkan wà tí ilẹ̀ kò lè gbà mọ́ra: ẹrú tí ó jọba, òmùgọ̀ tí ó jẹun yó, obinrin tí ayé kórìíra tí ó wá rí ọkọ fẹ́, ati iranṣẹbinrin tí ó gba ọkọ mọ́ ọ̀gá rẹ̀ lọ́wọ́.