Owe 18:4-5

Owe 18:4-5 YBCV

Ọ̀rọ ẹnu enia dabi omi jijìn, orisun ọgbọ́n bi odò ṣiṣàn. Kò dara lati ṣe ojuṣãju enia-buburu, lati bì olododo ṣubu ni idajọ.