Owe 18:4-5
Owe 18:4-5 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ọ̀rọ ẹnu enia dabi omi jijìn, orisun ọgbọ́n bi odò ṣiṣàn. Kò dara lati ṣe ojuṣãju enia-buburu, lati bì olododo ṣubu ni idajọ.
Pín
Kà Owe 18Ọ̀rọ ẹnu enia dabi omi jijìn, orisun ọgbọ́n bi odò ṣiṣàn. Kò dara lati ṣe ojuṣãju enia-buburu, lati bì olododo ṣubu ni idajọ.