ÌWÉ ÒWE 18:4-5

ÌWÉ ÒWE 18:4-5 YCE

Ọ̀rọ̀ ẹnu eniyan dàbí odò jíjìn, orísun ọgbọ́n dàbí omi odò tí ń tú jáde. Kò dára kí á ṣe ojuṣaaju sí eniyan burúkú, tabi kí á dá olódodo ní ẹjọ́ ẹ̀bi.