Owe 15:29-30

Owe 15:29-30 YBCV

Oluwa jina si awọn enia-buburu; ṣugbọn o gbọ́ adura awọn olododo. Imọlẹ oju mu inu dùn; ihin rere si mu egungun sanra.