Owe 15:29-30
Owe 15:29-30 Bibeli Mimọ (YBCV)
Oluwa jina si awọn enia-buburu; ṣugbọn o gbọ́ adura awọn olododo. Imọlẹ oju mu inu dùn; ihin rere si mu egungun sanra.
Pín
Kà Owe 15Oluwa jina si awọn enia-buburu; ṣugbọn o gbọ́ adura awọn olododo. Imọlẹ oju mu inu dùn; ihin rere si mu egungun sanra.