Owe 14:7-8

Owe 14:7-8 YBCV

Kuro niwaju aṣiwere, ati lọdọ ẹniti kò ni ète ìmọ. Ọgbọ́n amoye ni ati moye ọ̀na rẹ̀: ṣugbọn iwere awọn aṣiwere li ẹ̀tan.