Owe 14:7-8
Owe 14:7-8 Bibeli Mimọ (YBCV)
Kuro niwaju aṣiwere, ati lọdọ ẹniti kò ni ète ìmọ. Ọgbọ́n amoye ni ati moye ọ̀na rẹ̀: ṣugbọn iwere awọn aṣiwere li ẹ̀tan.
Pín
Kà Owe 14Owe 14:7-8 Bibeli Mimọ (YBCV)

Kà Owe 14