Owe 12:27-28

Owe 12:27-28 YBCV

Ọlẹ enia kò mu ohun ọdẹ rẹ̀; ṣugbọn lati jẹ alãpọn enia, ọrọ̀ iyebiye ni. Li ọ̀na olododo ni ìye; ikú kò si loju ọ̀na otitọ.