Owe 12:27-28
Owe 12:27-28 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ọlẹ enia kò mu ohun ọdẹ rẹ̀; ṣugbọn lati jẹ alãpọn enia, ọrọ̀ iyebiye ni. Li ọ̀na olododo ni ìye; ikú kò si loju ọ̀na otitọ.
Pín
Kà Owe 12Ọlẹ enia kò mu ohun ọdẹ rẹ̀; ṣugbọn lati jẹ alãpọn enia, ọrọ̀ iyebiye ni. Li ọ̀na olododo ni ìye; ikú kò si loju ọ̀na otitọ.