Owe 11:16-17

Owe 11:16-17 YBCV

Obinrin olore-ọfẹ gbà iyìn: bi alagbara enia ti igbà ọrọ̀. Alãnu enia ṣe rere fun ara rẹ̀: ṣugbọn ìka-enia nyọ ẹran-ara rẹ̀ li ẹnu.