ÌWÉ ÒWE 11:16-17

ÌWÉ ÒWE 11:16-17 YCE

Obinrin onínúrere gbayì, ṣugbọn ọrọ̀ nìkan ni ìkà yóo ní. Ẹni tí ó ṣoore ṣe é fún ara rẹ̀, ẹni tí ó sì ń ṣìkà ó ń ṣe é fún ara rẹ̀.