Mak 2:14

Mak 2:14 YBCV

Bi o si ti nkọja lọ, o ri Lefi ọmọ Alfeu, o joko ni bode, o si wi fun u pe, Mã tọ̀ mi lẹhin. Ó si dide, o tọ̀ ọ lẹhin.

Àwọn fídíò fún Mak 2:14