Mak 2:14
Mak 2:14 Yoruba Bible (YCE)
Bí ó ti ń lọ, ó rí Lefi ọmọ Alfeu tí ó jókòó níbi tí ó ti ń gba owó-odè. Ó wí fún un pé, “Máa tẹ̀lé mi.” Lefi bá dìde, ó sì tẹ̀lé e.
Pín
Kà Mak 2Mak 2:14 Bibeli Mimọ (YBCV)
Bi o si ti nkọja lọ, o ri Lefi ọmọ Alfeu, o joko ni bode, o si wi fun u pe, Mã tọ̀ mi lẹhin. Ó si dide, o tọ̀ ọ lẹhin.
Pín
Kà Mak 2