Luk 4:13-14

Luk 4:13-14 YBCV

Nigbati Èṣu si pari idanwò na gbogbo, o fi i silẹ lọ di sã kan. Jesu si fi agbara Ẹmí pada wá si Galili: okikí rẹ̀ si kàn kalẹ ni gbogbo àgbegbe ti o yiká.

Àwọn fídíò fún Luk 4:13-14