Luk 4:13-14
Luk 4:13-14 Bibeli Mimọ (YBCV)
Nigbati Èṣu si pari idanwò na gbogbo, o fi i silẹ lọ di sã kan. Jesu si fi agbara Ẹmí pada wá si Galili: okikí rẹ̀ si kàn kalẹ ni gbogbo àgbegbe ti o yiká.
Pín
Kà Luk 4Nigbati Èṣu si pari idanwò na gbogbo, o fi i silẹ lọ di sã kan. Jesu si fi agbara Ẹmí pada wá si Galili: okikí rẹ̀ si kàn kalẹ ni gbogbo àgbegbe ti o yiká.