Joh 11:33

Joh 11:33 YBCV

Njẹ nigbati Jesu ri i, ti o nsọkun, ati awọn Ju ti o ba a wá nsọkun pẹlu rẹ̀, o kerora li ọkàn rẹ̀, inu rẹ̀ si bajẹ

Àwọn fídíò fún Joh 11:33