JOHANU 11:33

JOHANU 11:33 YCE

Nígbà tí Jesu rí i tí ó ń sunkún, tí àwọn Juu tí ó bá a jáde tún ń sunkún, orí rẹ̀ wú, ọkàn rẹ̀ wá bàjẹ́.

Àwọn fídíò fún JOHANU 11:33