I. Tim 4:4-5

I. Tim 4:4-5 YBCV

Nitori gbogbo ohun ti Ọlọrun dá li o dara, kò si ọkan ti o yẹ ki a kọ̀, bi a ba fi ọpẹ́ gbà a. Nitori a fi ọ̀rọ Ọlọrun ati adura yà a si mimọ́.